SSS3 Yoruba Scheme of Work

Complete Yoruba curriculum for Senior Secondary School 3 students

SSS3 Yoruba Curriculum Overview

This comprehensive Yoruba scheme of work for SSS3 covers advanced language skills, culture, literature, and social aspects essential for Senior Secondary School 3 students in Nigeria.

FIRST TERM

Asa, Ede Ati Litireso I

Ede:
  • 1. Atunyewo leta aigbagbefe
  • 2. Atunyewo isori oro
  • 3. Aayan Ogbufo
  • 4. Aranmo
Asa:
  • 1. Iwa omoluabi
  • 2. Eto Ebi
  • 3. Itesiwaju Ere Idaraya
  • 4. Atunyewo Eto Iselu
  • 5. Igbeyawo isinku ati ogun jiye
Litireso:
  • 1. Kiko ni mimo ise onkowe atinuda ( Ewi itan-aroso ere-onitan)
  • 2. Ewi Apileko
  • 3. itupale asayan iwe itan arose meji

SECOND TERM

Asa, Ede Ati Litireso II

Ede:
  • 1. Pipaje ati isunki
  • 2. Atunyewo onka figo
  • 3. Atunyewo Akaye
  • 4. Atunyewo gbogbo isori gbolohun
  • 5. Atunyewo Aroko ati Aroko Alariiyanjiyan
  • 6. Itesiwaju ihun gbolohun : orisirisi awe gbolohun
Asa:
  • 1. Eto isomoloruko ati oruko Yoruba
Litireso:
  • 1. Atunyewo itan arose oloro geere (gbogbo iwe)
  • 2. Atunyewo Ewi Alohun Apileko (gbogbo iwe)
  • 3. Atuupale iwe ere onitan (iwe meji)
  • 4. Itupale Ewi Alohun (Asayan iwe meji)

Learning Objectives:

Students will develop advanced Yoruba language skills, understand cultural practices and traditions, learn about literature and storytelling, and gain knowledge of Yoruba social systems essential for cultural preservation and language development.

Download Resources

Get the complete SSS3 Yoruba scheme of work in PDF format.

Download PDF

Need More Yoruba Resources?

Explore our comprehensive collection of Yoruba materials for SSS students.